operations |
comment | "parent_author":"",
"parent_permlink":"yoruba",
"author":"cryptokheart",
"permlink":"eto-isuna-ni-cryptocurrency-ni-irorun",
"title":"Eto Isuna ni Cryptocurrency Ni Irorun",
"body":"Titele ipase baye ba se n yi,
kama bawon yi ni ona to daraju lati ma se deni igbagbe seyin.\n\nNinu eka eto inawo toloyinbo npe ni Cryptocurrency,
a ti sun kuro ni nilo lati se iforukosile ki a to le yi owo pada.\n\nOniruuru wahala lo ma n jeyo bawon eyan ba fe yi owo pada tabi tawon eyan ba nilo lati na lara dukia tabi ohun ini won nibi ti won o ti nilo lati se oniruuru ipele iforukosile KYC. Sibe,
pelu gbogbo wahala iforukosile KYC yi,
o tun seese ki o ma kese jari latari awon iyato die die to ma n jeyo lakoko iforukosile bii ki irun to wa ninu aworan ti elomi ya,
ko yato si bohun fun ra re se ri\n\nSugbon ninu eka eto inawo Cryptocurrency,
ko nilo gbogbo wahala yi,
abo to peye si wa fun gbogbo ohun to banise pelu re.\n\nNi awon orileede bi ti Nigeria,
fun apere,
oruko to n be lori iwe isanwo ina lee yato si oruko awon to n gbe ninu ile tiwon ti n fi iwe na sanwo ina tori pe won ya ile na gbe ni,
kii se ile won. Bi enikeni ba fe se iforukosile pelu iru iwe bee,
oseese kawon ile ifowopamo ma gbaa nitoripe kii se oruko onitohun lon be lori iwe isanwo ina ohun. Bee sire awon ile ifowopamo tabi ile ise eto isunna ma n fariga pe dandan ni ki gbogbo iwe yi ati oruko eni to fe yo owo,
ki o bara mu.\n\nOo se ye dara re lamu pelu gbogbo wahala iforuko sile yi?\n\nItakun ero ayelujara https:\/\/changenow.io ni mo n lo mo si n gbadun re daada. Opolopo eto owo ni mo ti se lori itakun ayelujara yi lai mu wahala kankan dani.\n\nEyi ni itakun ayelujara akoko to n ri s'oro eto inawo Cryptocurrency to fun mi l'anfani lati se ohun gbogbo ti mo fe se lai si gbogbo idamu iforukosile kin to le ri ohunkohun se.\n\nSugbon lati pinwo awon oni jibiti,
tabi ti nkankan ba mu ifura dani ti ChangeNow si sawari re,
oseese ki Iforukosile KYC di dandan.",
"json_metadata":" \"tags\":[\"yoruba\",
\"article\",
\"cryptocurrency\",
\"exchange\",
\"bitcoin\" ,
\"links\":[\"https:\/\/changenow.io\" ,
\"app\":\"steemit\/0.2\",
\"format\":\"markdown\" " |